Buruburu by David Oke Ags

David Oke Ags

Mo ba buruburu niwaju Oluwa
(I bow in awe before Lord )
Mo juba re Oba awon oba
(I salute you The King of kings)
Awamaridi, Awimayehun
(Mystery, One whose words never change)
Aditi gb’ohun re, o ba buruburu
(The deaf hears your voice and rolls in awe before you)
ise owo re, o jo mi loju lopolopo
(The works of your hands amaze me)
Awon oke nla nla, orisirisi awo loju orun
(Huge mountains, diverse colors in the sky)
Opolopo eda lo n be ninu okun
(There are countless of creatures in the sea)
Iyanu ni O Oluwa,
Comments
;